Use of the Shortcode Made Easier In Nigerian Languages

3 Feb    Uncategorized -
Feb 3

Use of the Shortcode Made Easier In Nigerian Languages


Our very first translation is here and it is in Yoruba. We are thankful to Mr. Olanbiwoninu Razaq Adeola Adewunmi for helping with the translation. Can you help translate this to your language so that we can produce into a jingle?

Ǹjẹ́ o nílò ìrànlówó lórí ọmọ rẹ tí ń ṣòjòjò látàrí pé abi láì tójó ? O lè fi àtèjísé ránsé síwa l’óri ẹ̀rọ ìbánisòrò rẹ, sí nọ́mbà yìí 32811 ní ọ̀nà yí : prematurebaby ibi tí à ń gbé sí nọ́mbà yìí 32811

Fún àpẹẹrẹ : prematurebaby Èkó sí nọ́mbà yìí 32811.

Ànfàní yìí wá pẹ̀lú :

Òfin, ìlànà àti ìgbésè.

Please follow and like us:

By-

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *